Ìfihàn 15:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì ń kọ orin ti Móṣè, ìránṣẹ́ Ọlọ́run, àti orin ti Ọ̀dọ́-Àgùntàn, wí pé:“Títóbi àti ìyanu ni àwọn iṣẹ́ rẹ,Olúwa Ọlọ́run Olodùmarè;òdodo àti òtítọ́ ni ọ̀nà rẹ̀,ìwọ Ọba àwọn orílẹ̀-èdè.

Ìfihàn 15

Ìfihàn 15:1-6