Ìfihàn 14:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì wo, si kíyèsí i, Ọ̀dọ́-Àgùntàn náà dúró lórí Òkè Síónì, àti pẹ̀lú rẹ̀ ọ̀kẹ́ méje-ó-lé ẹgbàájì ènìyàn; wọ́n ní orúkọ rẹ̀, àti orúkọ baba rẹ̀ tí a kọ sí iwájú-orí wọn.

Ìfihàn 14

Ìfihàn 14:1-11