Ìfihàn 13:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Niyìn ni ọgbọ́n gbé wà. Ẹni tí o bá ní òye, kí o ka nọ́ḿbà tí ń bẹ̀ lára ẹranko náà: nítorí pé nọ́ḿbà ènìyàn ni, nọ́ḿbà rẹ̀ náà sì jẹ́ ẹgbẹ̀ta ọgọ́ta ẹẹ́fà. (666).

Ìfihàn 13

Ìfihàn 13:10-18