Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣọ́ọ̀lù sì dìde ní ilẹ̀; nígbà tí ojú rẹ̀ sì lá kò rí ohunkóhun; ṣùgbọ́n wọ́n fà á lọ́wọ́ wọ́n sì mú un wá sí Dámásíkù.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:6-10