Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọkùnrin tí wọ́n sì ń bá Sọ́ọ̀lù lọ àjò dúró, wọn kò sì le sọ ohun kan, wọn gbọ́ ohùn náà ṣùgbọ́n wọn kò rí ẹnìkan.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:3-9