Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pétérù sì wí fún un pé, “Áénéà, Jésù Kírísítì mú ọ láradá; dìde kí ó sì tún àkéte rẹ ṣe.” Ó sì dìde lójúkan náà.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:29-39