Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbẹ̀ ni ó rí ọkùnrin kan ti a pè ní Áénéà tí ó ti dùbúlẹ̀ lórí àkéte ni ọdún mẹ́jọ, ó ní àrùn ẹ̀gbà.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:24-38