Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí àwọn arákùnrin sì mọ̀, wọ́n mú sọ̀kalẹ̀ lọ sí Kesaríà, wọ́n sì rán an lọ sí Tásísì.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:29-38