Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ń fi ìgboyà wàásù ni orúkọ Jésù Olúwa, ó ń sọ̀rọ̀ lòdì sí àwọn ará Hélénì, ó sì ń jà wọ́n níyàn; ṣùgbọ́n wọn ń pète láti pa a.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:22-39