Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ìjọ àwọn ènìyàn gbọ̀, tí wọn sì rí iṣẹ́ àmì tí Fílípì ń ṣe, gbogbo wọn sì fi ọkan kan fíyèsí ohun tí ó ń sọ.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:1-12