Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fílípì sì sọ̀kalẹ̀ lọ sí ìlú Samaríà, ó ń wàásù Kírísítì fún wọn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:2-10