Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ibi-ìwé-mímọ́ tí Ìwẹ̀fà náà ń kà náà ni èyí:“A fà á bí àgùntàn lọ fún pípa;àti bí ọ̀dọ́-àgùntàn tí ń dákẹ́ níwájú olúrẹ́run rẹ̀,bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni kò wí ohun kan.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:31-34