Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ kò ni ipa tàbí ìpín nínú ọ̀ràn yìí, nítorí ọkàn rẹ kò ṣe déedé níwájú Ọlọ́run.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:17-28