Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Símónì rí i pé nípa gbígbe ọwọ́ leni ni a ń ti ọwọ́ àwọn àpósítélì fi Ẹ̀mí Mímọ́ fún ni, ó fi owó lọ̀ wọ́n,

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:13-21