Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Pétérù àti Jòhánù gbé ọwọ́ lé wọn, wọn sí gba Ẹ̀mí Mímọ́.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:12-21