Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí àwọn àpósítélì tí ó wà ní Jerúsálémù sí gbọ́ pé àwọn ara Samaríà ti gba ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, wọ́n rán Pétérù Àti Jòhánù sí wọn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:11-17