Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Símónì tikararẹ̀ sì gbàgbọ́ pẹ̀lú nígbà ti a sì bámitíìsì rẹ̀, ó sì tẹ̀ṣíwájú pẹ̀lú Fílípì, ó wo iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ agbára tí ń ti ọwọ́ Fílípì ṣe, ẹnu sì yà á.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:4-20