Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wí pé ‘Èmi ni Ọlọ́run àwọn baba rẹ, Ọlọ́run Ábúráhámù àti Ọlọ́run Ísáákì, àti Ọlọ́run Jákọ́bù,’ Mósè sì wárìrì pẹ̀lú ìbẹ̀rù, kò sì dàṣà láti wò ó mọ́.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:28-35