Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Mósè sì rí i, ẹnu yà á sí ìran náà; nígbà tí ó sì súnmọ́ ọn láti wò ó fín, ohùn Olúwa kọ sí i,

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:27-35