Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì kọ́ Mósè ni gbogbo ọgbọ́n ara Íjíbítì, ó sì pọ̀ ni ọ̀rọ̀ àti ní ìṣe.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:14-29