Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọn sí gbe é sọnù, ọmọbìnrin Fáráò gbé e, ó sì tọ ọ́ dàgbà gẹ́gẹ́ bí ọmọ ara rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:12-30