Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni olorí àlùfáà wí pé, “Òtítọ́ ha ni àwọn ẹ̀sùn tí wọ́ fi kàn ọ́ bí?”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:1-10