Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn tí ó sì jókò ni àjọ ìgbìmọ̀ tẹjúmọ́ Sítéfánù, wọ́n sì rí ojú rẹ̀ dàbí ojú ańgẹ́lì.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6:11-15