Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àwa bá ilé túbú ni títí pinpin, àti àwọn olùsọ́ dúró lóde níwájú ilẹ́kùn; ṣùgbọ́n nígbà tí àwa sí ilẹ̀kùn, àwa kò bá ẹnìkan nínú túbú.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:15-33