Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn olùsọ́ dé ibẹ̀ wọn kò sì rí wọn nínú túbú, wọn pàda wá, wọn sí sọ fún wọn pé,

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:20-23