Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó bá ṣe pé a ń wádìí wa lónì ní tí iṣẹ́ rere ti a ṣe lára abirùn náà, bí a ti ṣe mú ọkùnrin yìí láradá,

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:8-19