Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Pétérù kún fún Ẹ̀mí Mímọ́, ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ̀yin olórí àti ẹ̀yin alàgbà àwọn ènìyàn!

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:1-12