Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú bí wọn, nítorí tí wọn kọ́ àwọn ènìyàn, wọ́n sì ń wàsúù àjíǹde kúrò nínú òkú nínú Jésù.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:1-4