Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Pétérù àti Jòhánù dáhùn, wọ́n sì wí fún wọn pé, “Bí ó bá tọ́ lójú Ọlọ́run láti gbọ́ tiyín ju ti Ọlọ́run lọ ẹ gbà á rò.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:10-21