Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì pè wọ́n, wọ́n pàsẹ fún wọn, kí wọn má ṣe sọ̀rọ̀ tàbí kọ́ni rárá mọ́ ní orúkọ Jésù.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:9-20