Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ń fò sókè, ó dúró, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí rìn, ó sì bá wọn wọ inú tẹ́ḿpìlì lọ, ó ń rìn, ó sì ń fò, ó sì yín Ọlọ́run.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:4-16