Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì fà á lọ́wọ́ ọ̀tún, ó sì gbé dìde; lójúkán náà ẹsẹ̀ rẹ̀ àti egungun kókósẹ̀ rẹ̀ sì mókun.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:1-14