Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ń wàásù ìjọba Ọlọ́run, ó ń fi ìgboyà kọ́ni ní àwọn ohun tí i ṣe ti Jésù Kírísítì Olúwa, ẹnìkan kò dá a lẹ́kun.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:25-31