Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pọ́ọ̀lù sì gbé ilé àgbàwọ̀ rẹ̀ lọ́dún méjì gbáko, ó sì ń gbà gbogbo àwọn tí ó wọlé tọ̀ ọ́ wá.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:27-31