Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pọ́ọ̀lù sì wí pé, “Mo dúró níwájú ìtẹ́-ìdájọ́ Késárì níbi tí ó yẹ kí a ṣe ẹjọ́ mí: èmi kò ṣẹ àwọn Júù, bí ìwọ pẹ̀lú ti mọ̀ dájú.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:8-11