Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn tí ó sì wà pẹ̀lú mi rí ìmọ́lẹ̀ náà nítòótọ́, ṣùgbọ́n wọn kò gbọ́ ohùn ẹni tí ń bá mi sọ̀rọ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:1-11