Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mo sì béèrè pé, ‘Ta ni ìwọ́, Olúwa?’“Ó sì dá mi lóhùn pé, ‘Èmi ni Jésù tí Násárétì, ẹni tí ìwọ́ ń ṣe inúnibíni sí.’

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:1-14