Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Júù ni èmi í ṣe, a bí mi ni Tásọ́sì ìlú kan ní Kílíkíà, ṣùgbọ́n tí a tọ́ mi dàgbà ni ìlú yìí. Ní abẹ́ ẹsẹ̀ Gàmálíẹ́lì ni a sì gbé kọ́ mi ní òfin àwọn baba wa, tí mo sì jẹ́ onítara fún Ọlọ́run àní gẹ́gẹ́ bí gbogbo yin tí rí ni òní.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:1-13