Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọ́n sì tí fẹ́rẹ̀ mú Pọ́ọ̀lù wọ inú àgọ́ àwọn ológun lọ, ó wí fún olórí-ogun pé, “Èmi ha lè bá ọ sọ̀rọ̀ bí?”Ó sì dáhùn wí pé, “Ìwọ mọ èdè Gíríkì bí?

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:30-40