Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ọ̀pọ̀ ènìyàn rọ́ tẹ̀lé e, wọ́n ń kígbe pé, “Mú un kúrò!”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:27-40