Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó sì kí wọn tan, ó ròyìn lẹsẹẹsẹ ohun gbogbo tí Ọlọ́run ṣe láàrin àwọn aláìkọlà nípa iṣẹ́-ìránṣẹ́ rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:16-28