Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ijọ́ kejì, a bá Pọ́ọ̀lù lọ sọ́dọ̀ Jákọ́bù; gbogbo àwọn alàgbà sì wà níbẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:10-20