Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì mú ọmọkùnrin náà bọ̀ láàyè, inú gbogbo wọn sì dún lọ́pọ̀lọpọ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:4-14