Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó sì tún gòkè lọ, ó sì jẹ oúnjẹ́ Olúwa, ó sì sọ̀rọ̀ pẹ́ títí ó fi di àfẹ̀mọ́júmọ́, nígbà náà ni ó sì lọ.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:9-15