Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn Júù olùfọkànsìn láti orílẹ̀-èdè gbogbo lábẹ́ ọ̀run sì ń gbé Jerúsálémù.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:4-12