Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo wọn sì kún fún Ẹ̀mí Mímọ́, wọn sì bẹ̀rẹ̀ sí í fi èdè mìíràn sọ̀rọ̀, gẹ́gẹ́ bí Ẹ̀mí ti fi fún wọn ni ohùn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:1-14