Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n fi ọkàn kan dúró lójoojúmọ́ nínú tẹ́mpílì. Wọ́n ń bu àkàrà ní ilé wọn, wọn ń fi inú dídùn àti ọkàn òtítọ́ jẹ oúnjẹ wọn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:37-47