Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn si ń ta ohun ìní àti ẹrù wọn, wọn sì ń pín wọn fún olúkúlùkù, gẹ́gẹ́ bí ẹnikẹ́ni tí í ṣe aláìní.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:35-47