Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ti gbé ga sí ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run, ó ti gba ìlérí Ẹ̀mí Mímọ́ láti ọ̀dọ̀ Baba, ó tu èyí tí ẹ̀yin rí àti gbọ́ nísinsìyìí sítá.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:29-37