Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù náà yìí ni Ọlọ́run ti jí díde sí ìyè, àwa pẹ̀lú sì jẹ́rìí sí èyí.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:22-37